Search

Wednesday 6 January 2016

Lekan si bi orun ti nran

Lekan si bi orun ti nran


Verse 1
Lekan si bi orun ti nran
Awa mbe Olorun
Pe ki mole Re ailopin
S'amona wa loni

Verse 2
K'a mase da esekese
K'a ma si ro ibi
K'a ni otito gan lenu
Ati ife l'okan

Verse 3
Lojo oni Olugbala
K'ari  iranwo Re
Lati gba wa lowo Esu
Ti ndodo wa kiri

Verse 4
Ki ise wa l'ojojumo
Ma je fun iyin Re
Be l'o ma bukun ise wa
T'a mo ere ninu Re

Verse 5
Jek'a fi iwontunwonsi
Kawo 'fekufe wa
Ki gberaga asan ara
Ma bori okan wa

Verse 6
Olorun Baba at'Omo
Ati Emi mimo
Ni ki Eda at'Angeli
F'ogo ailopin fun.
Amin

English Translation- Once more the sun is beaming bright

No comments:

Post a Comment