Search

Wednesday 14 October 2015

Mo f'iyin ailopin fun Olorun Baba

 
Mo f'iyin ailopin

Verse 1
Mo f'iyin ailopin
Fun Olorun Baba
Fun ore aye mi
At' ireti t'orun
O ran Omo Re ayanfe
Lati ku fun ese aye

Verse 2
Mo f'iyin ailopin
Fun Olorun Omo
T'O f'eje Re we wa
Kuro ninu egbe
Nisisiyi O wa l'Oba
O nri eso irora Re

Verse 3
Mo f'iyin ailopin
Fun Olorun Emi
Eni f'agbara Re
So elese d'aye
O pari ise igbala
O si fi ayo kun okan

Verse 4
Mo f'iyin ailopin
Fun Olodumare
Wo Ologo meta
sugbon okan soso
B'O ti ju imo wa lo ni
A o ma f'igbagbo yin O




English translation-We give immortal praise to God the Father's love

9 comments: